June 21, 2025

Words and meanings.(A Peter fatomilola's Ịfa concrete free verse.)part two

Oni ọgbọ bi 
Ọrụnmila soro
be si
Oni ifa ni
ewi fun
moni moni
Kọ ma
mo ni lo 
Ifa ni ewi
monyan monyan
Kọ mon 
monyan.
ire kikin 
Kọ ni 
nne nini
ka Mọn
ra eni 
Odifa fun
Ọrụnmila 
Ifa lo mon 
Olokun 
seni aje
ebo ni won 
Niko se 
Osetan 
Ojafun 
Odele olokun
Ire Owo ire omo
Ire ya
On lorunmila
Kọ wa le"
This oracle 
Shed light to
His puzzle 
Known or
translated as 
Oro pelu itumo"
meaning 
"words and meanings 
Or using mortal influence 
to derive wisdom"







No comments:

Post a Comment