Bimo ba difa fun ifa ,bimo ba difa eni ifa
Omo ifa berekete ni je
Bimo ba difa fun opele Omo opele ni je
Odifa fun melo melo odi fa fun okele enun
Ko ma ja bo lenun eni
Odifa fun akalamagboo odifa fun opele onifa
Kaye ma suni Kaye legbe ni Kaye le gbani
Odifa fun orire eni ko ma pada lehin eni
Kori eni gbeni ko ba ni de ibire ko ri eni gba ni
Ko gbe ni de le ore Ile orire eni ko ma pa da leyin eni
No comments:
Post a Comment